Yoruba Hymn APA 95- Olorun at’ ireti mi

Yoruba Hymn APA 95- Olorun at’ ireti mi

 Yoruba Hymn  APA 95-  Olorun at’ ireti mi

APA 95 

1. Olorun at’ ireti mi,

 Oro Re l’ onje mi,

 Owo Re gbe mi ro l’ ewe

 Ati l’ odomode.


2. Sibe mo nrohun iyanu

 T’ O nse ni ododun;

 Mo fi ojo mi ti o ku

 S’ iso Tire nikan.


3. Ma ko mi, nigba ’gbara ye,

 Ti ewu ba bo mi,

 Kio go Re ran yi mi ka

 Nigbati mo ba ku. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 95 -Olorun at’ ireti mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم