Yoruba Hymn APA 94 - B’ orun l’ aiduro ti rin

Yoruba Hymn APA 94 - B’ orun l’ aiduro ti rin

Yoruba Hymn  APA 94 - B’ orun l’ aiduro ti rin

APA 94

 1. B’ orun l’ aiduro ti rin,

 La odun ti o lo ja,

 Be l’ opo ti d’ opin won

 A ki o si ri won mo.


2. A so won l’ ojo lailai,

 Tiwon pari li aiye;

 Awa duro die na,

 Y’o tip e to, a ko mo.


3. Gb’ ope f’ anu t’ o koja,

 Tun dari ese ji wa;

 Ko wa b’ a ti wa, k’ a ma

 Se ’ranti aiye ti mbo.


4. Bukun f’ewe at’ agba,

 F’ ife Oluwa kun wa;

 ’Gba ojo aiye wa pin

 K’ a gbe odo Re l’ oke. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 94 - B’ orun l’ aiduro ti rin . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم