Yoruba Hymn APA 84- Ayo kun okan wa loni

Yoruba Hymn APA 84- Ayo kun okan wa loni

Yoruba Hymn  APA 84- Ayo kun okan wa loni

APA 84

 1. Ayo kun okan wa loni

 A bi Omo Oba;

 Opo awon ogun orun,

 Nso ibi Re loni:

 E yo, Olorun d’ enia,

 O wa joko l’ aiye;

 Oruko wo l’ o dun to yi

 Emmanuel.


2. A wole n’ ibuje eran,

 N’ iyanu l’a josin:

 Ibukun kan ko ta ’yi yo,

 Ko s’ ayo bi eyi

 E yo, Olorun, &c.


3. Aiye ko n’ adun fun wa mo,

 ’Gbati a ba nwo O;

 L’owo Wundia iya Re,

 ’Wo Omo Iyanu.

 E yo, Olorun, &c.


4. Imole lat’ inu ’Mole,

 Tan ’mole s’ okun wa;

 K’ a le ma fi isin mimo

 Se ’ranti ojo Re.

 Eyo, Olorun d’ enia,

 O wa joko l’ aiye;

 Oruko wo l’ o dun to yi

 Emmanuel. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 84- Ayo kun okan wa loni . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم