Yoruba Hymn APA 593 - Ore-ofe! ohun

Yoruba Hymn APA 593 - Ore-ofe! ohun

 Yoruba Hymn  APA 593 - Ore-ofe! ohun

APA 593

1. Ore-ofe! ohun

 Adun ni l’ eti wa:

 Gbohun-gbohun re y’o gba orun kan,

 Aiye o gbo pelu.

 Ore-ofe sa,

 N’ igbekele mi;

 Jesu ku fun araiye,

 O ku fun mi pelu.


2. Ore-ofe lo ko

 Oruko mi l’orun;

 L’o fi mi fun Odaguntan,

 T’o gba iya mi je.

 Ore-ofe sa, &c

 

3. Ore-ofe to mi

 S’ ona alafia;

 O ntoju mi lojojumo,

 Ni irin ajo mi.

 Ore-ofe sa, &c 


4. Ore-ofe ko mi,

 Bi a ti ’gbadura;

 O pa mi mo titi d’ oni,

 Ko si je ki nsako.

 Ore-ofe sa, &c


5. Je k’ ore-ofe yi

 F’ agbara f’ okan mi;

 Ki nle fi gbogbo ipa mi

 At’ ojo mi fun O.

 Ore-ofe sa, &c .Amin



Yoruba Hymn  APA 593 - Ore-ofe! ohun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 593-  Ore-ofe! ohun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم