Yoruba Hymn APA 590 - Wo oro t’o dun julo

Yoruba Hymn APA 590 - Wo oro t’o dun julo

 Yoruba Hymn  APA 590 - Wo oro t’o dun julo

APA 590

1. ’Wo oro t’o dun julo,

 Ninu eyit’ a ri

 Ileri at’ imuse

 Awamaridi ni:

 Nigba ekun at’ ayo,

 ’Yemeji at’ eru,

 Mo gbo Jesu wipe, “Wa,”

 Mo si lo sodo Re.

 Wa, wa sodo Mi,

 Wa, wa sodo Mi,

 Alare t’orun nwo,

 Wa ! wa sodo Mi.


2. Emi mi, ma sako lo

 Kuro lod’ Ore yi!

 Sunmo O, a! sunmo O,

 Ba gbe titi d’opin;

 A! alailera l’emi,

 Ese mi papoju;

 Mo nsako nigbagbogbo,

 Mo si tun pada wa.

 Wa! wa sodo Mi! &c.


3. Ma fa mi sunm’ odo Re,

 Ki “Wa” yi ba le je

 Ohun ti a fo jeje

 F’ eni t’o sunmo O;

 Okun ati oke nla

 Ki yio da mi duro

 Lati di owo Re mu,

 Nigbat’ O wipe, “Wa.”



 Yoruba Hymn  APA 590 - Wo oro t’o dun julo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 590- Wo oro t’o dun julo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

 Wa! wa sodo Mi! &c. Amin.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم