Yoruba Hymn APA 561 - Gbogbo aiye, gbe Jesu ga

Yoruba Hymn APA 561 - Gbogbo aiye, gbe Jesu ga

Yoruba Hymn  APA 561 - Gbogbo aiye, gbe Jesu ga

APA 561

 1. Gbogbo aiye, gbe Jesu ga,

 Angel, e wole fun;

 E mu ade oba Re wa,

 Se l’Oba awon oba.


2. E se l’Oba, enyin Martyr,

 Ti npe ni pepe Re;

 Gbe gbongo-igi Jesse ga,

 Se l’Oba awon oba.


3. Enyin iru-omo Israel,

 Ti a ti rapada;

 E ki Enit’ o gba nyin la,

 Se l’Oba awon oba.


4. Gbogbo enia elese,

 Ranti ‘banuje nyin;

 E te ‘kogun nyin s’ese Re,

 Se l’Oba awon oba.


5. Ki gbogbo orile-ede,

 Ni gbogbo agbaiye;

 Ki nwon ki, “Kabiyesiel,”

 Se l’Oba awon oba.


6. A ba le pel’ awon t’orun,

 Lati ma juba Re;

 K’a ba le jo jumo korin,

 Se l’Oba awon oba. Amin.



Yoruba Hymn  APA 561 - Gbogbo aiye, gbe Jesu ga

This is Yoruba Anglican hymns, APA 561-  Gbogbo aiye, gbe Jesu ga. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم