Yoruba Hymn APA 514 - Gbat’ a kun fun banuje

Yoruba Hymn APA 514 - Gbat’ a kun fun banuje

 Yoruba Hymn  APA 514 - Gbat’ a kun fun banuje

APA 514

1. Gbat’ a kun fun banuje,

 Gb’ omije nsan loju wa;

 Gbat’ a nsokun, t’a nsofo,

 Olugbala, gbo ti wa.


2. ’Wo ti gbe ara wa wo;

 O si mo banuje wa;

 O ti sokun bi awa,

 Olugbala, gbo ti wa.


3. ’Wo ti teriba fun ’ku;

 ’Wo ti t’eje Re sile;

 A te O si posi ri;

 Olugbala, gbo ti wa.


4. Gbat’ okan wa ba baje,

 Nitori ese t’a da;

 Gbat’ eru ba b’okan wa,

 Olugbala, gbo ti wa.


5. ’Wo ti mo eru ese,

 Ese ti ki ’se Tire:

 Eru ese na l’O gbe,

 Olugbala, gbo ti wa.


6. O ti silekun iku,

 O ti s’etutu f’ ese;

 O wa low’ otun Baba,

 Olugbala, gbo ti wa.



Yoruba Hymn  APA 514 - Gbat’ a kun fun banuje

This is Yoruba Anglican hymns, APA 514- Gbat’ a kun fun banuje . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم