Yoruba Hymn APA 506 - Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe

Yoruba Hymn APA 506 - Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe

 Yoruba Hymn  APA 506 - Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe

APA 506

1. Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe;

 Ara nni mi, gbo igbe mi:

 ’Gba ’san omi ba bori mi,

 Ma je k’ okan mi fasehin.


2. Iwo Ore alailera,

 Tani mba s’ aroye mi fun?

 Bikose ’Wo nikansoso,

 T’ O npe otosi w’ odo Re?


3. Tal’ o sokun to lasan ri?

 ’Wo ko igbe enikan ri?

 Se Iwo ni O ti so pe,

 Enikan k’yo wa O lasan?


4. Eyi ’ba je ’binuje mi

 Pe, O ko ndahun adura;

 Sugbon ’Wo ti gbagbe mi;

 Iwo l’ O nse iranwo mi.

 

5. Mo mo pe alaini l’emi,

 Olorun ko ni gbagbe mi;

 Eniti Jesu mbebe fun,

 O bo lowo gbogbo ’yonu. Amin.



Yoruba Hymn  APA 506 - Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 506- Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم