Yoruba Hymn APA 497 - Emi o lo sodo Jesu
APA 497
1. Emi o lo sodo Jesu,
Eni npe mi pe ki’m wa,
Enit’ o se Olugbala
Fun elese bi emi.
2. Emi o lo sodo Jesu,
Irira at’ ibinu,
Ika at’ ise t’o buru,
T’enia nse, On ko ni.
3. Emi o lo sodo Jesu,
O dun mo mi kin se be;
Tal’ o fe mi bi ti Jesu,
Eniti o gba ni la?
4. Emi o lo sodo Jesu,
Jesu t’ o se Ore wa:
Anu wa ninu Re pupo,
Fun elese bi emi.Amin
Yoruba Hymn APA 497 - Emi o lo sodo Jesu
This is Yoruba Anglican hymns, APA 497- Emi o lo sodo Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals