Yoruba Hymn APA 490 - K’ awa to pari eko wa

Yoruba Hymn APA 490 - K’ awa to pari eko wa

Yoruba Hymn  APA 490 - K’ awa to pari eko wa

APA 490

 1. K’ awa to pari eko wa,

 Awa f’ iyin fun O;

 ’Tori ojo Re mimo yi,

 Jesu, Ore ewe.


2. Gbin oro Re si okan wa,

 Gba wa lowo ese;

 Ma je k’ a pada lehin Re,

 Jesu, Ore ewe.


3. Jesu jo bukun ile wa;

 K’ a lo ojo yi ’re;

 K’ a le ri aye l’ odo Re,

 Jesu, Ore ewe. Amin.



Yoruba Hymn  APA 490 - K’ awa to pari eko wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 490- K’ awa to pari eko wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم