Yoruba Hymn APA 471 - Olorun ite ogo Re
APA 471
1. Olorun ite ogo Re,
Yio wa titi lai;
Obi wa, talaka ni nwon,
F’ ibukun Re fun wa.
2. O wu O ni, lati se wa,
Ni talaka; sugbon
Ma se alabojuto wa,
’Gba ti a wa l’ aiye.
3. A mo, b’ a tile je Tire,
T’ a j’ oruko mo O,
A j’ alejo; sugbon se wa
L’ omo asayan Re.
4. Oluso Agutan wa, wo
Agbo kekere Re;
F’ ogo at’ opa Re to wa,
Omo agbo Tire. Amin.
Yoruba Hymn APA 471 - Olorun ite ogo Re
This is Yoruba Anglican hymns, APA 471- Olorun ite ogo Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals