Yoruba Hymn APA 470 - Gba Jesu wo tempili lo

Yoruba Hymn APA 470 - Gba Jesu wo tempili lo

Yoruba Hymn  APA 470 - Gba Jesu wo tempili lo

APA 470

 1. Gba Jesu wo tempili lo,

Ohun iyin l’a gbo;

Omode jewo eto Re,

Gbogbo won si ayo si.


2. Hosanna mu tempili ro,

Ahon pipo dalu;

Hosanna si Oba t’ orun,

S’ iru mimo Dafid.


3. Oluwa s’ ojo wa d’ otun,

’Gbat’ omode yin O:

Agbara at ’ore Re po

Bi t’ojo igbani. Amin.



Yoruba Hymn  APA 470 - Gba Jesu wo tempili lo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 470- Gba Jesu wo tempili lo . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم