Yoruba Hymn APA 465 - Jesu fe mi, mo mo be

Yoruba Hymn APA 465 - Jesu fe mi, mo mo be

Yoruba Hymn  APA 465 - Jesu fe mi, mo mo be

APA 465

 1. Jesu fe mi, mo mo be,

 Bibeli l’o so fun mi;

 Tire l’ awon omode,

 Nwon ko lagbara, On ni.


2. Jesu fe mi, En’ t’o ku

 Lati si orun sile;

 Yio we ese mi nu:

 Jeki omo Re wole.


3. Jesu fe mi sibe si,

 Bi emi tile s’aisan

 Lor’ akete aisan mi,

 Yio t’ ite Re wa so mi.


4. Jesu fe mi, y’o duro

 Ti mi ni gbogb’ ona mi,

 ’Gba mba f’aiye yi sile,

 Y’o mu mi re ’le orun. Amin.



Yoruba Hymn  APA 465 - Jesu fe mi, mo mo be

This is Yoruba Anglican hymns, APA 465- Jesu fe mi, mo mo be . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم