Yoruba Hymn APA 463 - Jesu onirele
APA 463
1. Jesu onirele,
Omo Olorun:
Alanu, olufe,
Gbo ’gbe omo Re.
2. Fi ese wa ji wa,
Si da wa n’ ide;
Fo gbogbo orisa
Ti mbe l’ okan wa.
3. Fun wa ni ominira,
F’ ife s’ okan wa;
Fa wa Jesu mimo,
S’ ibugbe l’ oke.
4. To wa l’ ona ajo,
Si je ona wa
La okun aiye ja
S’ imole orun.
5. Jesu onirele,
Omo Olorun;
Alanu, Olufe,
Gbo ’gbe omo Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 463 - Jesu onirele
This is Yoruba Anglican hymns, APA 463- Jesu onirele . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals