Yoruba Hymn APA 462 - Oluso-agutan l’ Olugbala wa

Yoruba Hymn APA 462 - Oluso-agutan l’ Olugbala wa

Yoruba Hymn  APA 462 - Oluso-agutan l’ Olugbala wa

APA 462

1. Oluso-agutan l’ Olugbala wa,

 B’ a ba wa l’ aiya Re, ki l’ a o beru?

 Sa je k’ a lo s’ ibi ti On nto wa si;

 Iba je asale, tab’ oko tutu.


2. Oluso-agutan, awa m’ ohun Re,

 Wo b’ oro kele Re ti mmokan wa dun.

 B’ o tile mba wa wi, jeje l’ ohun Re,

 Laisi Re lehin wa, awa o segbe.


3. Oluso-agutan ku f’ agutan Re.

 O f’ eje Re won awon agutan Re;

 O si fi ami Re s’ ara won, O ni,

 “Awon t’ o l’ Emi mi, awon ni t’ emi.”


4. Oluso-agutan, l’ abe iso Re,

 Bi koriko ba wa, ki y’o le se nkan.

 Bi awa tile nrin lojiji iku,

 Awa ki y’o beru, awa o segun. Amin.



Yoruba Hymn  APA 462 - Oluso-agutan l’ Olugbala wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 462- Oluso-agutan l’ Olugbala wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم