Yoruba Hymn APA 457 - Wa, Emi Mimo, wa

Yoruba Hymn APA 457 - Wa, Emi Mimo, wa

Yoruba Hymn  APA 457 - Wa, Emi Mimo, wa

APA 457

 1. Wa, Emi Mimo, wa,

 Gb’ ebe irele mi;

 Fi okan mi se ile Re,

 F’ ibukun Re sibe.


2. F’ ife Re s’ okan mi,

 K’ o si mu k’ o ma je

 Okan mimo, okan ayo,

 Ati ibugbe Re.


3. Ni igba ewe mi,

 Ki ore-ofe Re

 Mu opo eso rere wa,

 Fun ’yin Oruko Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 457 - Wa, Emi Mimo, wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 457- Wa, Emi Mimo, wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم