Yoruba Hymn APA 453 - Jesu a gb’ okan wa si O

Yoruba Hymn APA 453 - Jesu a gb’ okan wa si O

Yoruba Hymn  APA 453 - Jesu a gb’ okan wa si O

APA 453

 1. Jesu a gb’ okan wa si O,

 Mi Emi Re si won;

 Si baptis’ omode wonyi,

 Baptis’ won s’ iku Re.


2. K’ ororo Re wa l’ ori won (re),

 Si tune mi (re) won se:

 Ko oruko Re Oluwa,

 Si aiya gbogbo won.


3. Ki nwon (on) je iranse Tire,

 K’ oto s’ amure won (re):

 Ki nwon (on) s’ olupin iku Re,

 At’ omo lehin Re.


4. Gbin gbogbo wa si iku Re,

 K’ a le ni iye Re;

 K’ a le gbe agbelebu Re,

 K’ a le ni ade Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 453 - Jesu a gb’ okan wa si O

This is Yoruba Anglican hymns, APA 453- Jesu a gb’ okan wa si O. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم