Yoruba Hymn APA 452 - Wa, Emi Mimo, sokale

Yoruba Hymn APA 452 - Wa, Emi Mimo, sokale

Yoruba Hymn  APA 452 - Wa, Emi Mimo, sokale

APA 452

1. Wa, Emi Mimo, sokale,

 Onibaptisi okan wa,

 M’edidi majemu Re wa,

 K’ o si se eri omi yi.

2. Tu agbara nla Re jade,

 K’ o si won eje etutu;

 Ki Baba, Omo, at’ Emi,

 Jo so (won) o d’ omo Olorun. Amin.

Yoruba Hymn  APA 452 - Wa, Emi Mimo, sokale

This is Yoruba Anglican hymns, APA 452- Wa, Emi Mimo, sokale. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم