Yoruba Hymn APA 450 - Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re
APA 450
1. Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re,
B’ olus’agutan rere,
Ti ’sike awon t’o dera,
Ti ’gb’ awon odo mora.
2. Jowo! gba omode wonyi,
F’ anu gba won mo aiya;
Gbangba l’o daniloju pe,
Ewu ki y’o wu won n’be.
3. Nibe, nwon ko ni sako mo,
Ekun ki y’o le pa won;
Je ki ’ronu ife nla Re
Dabo won l’ ona aiye.
4. N’nu papa Re oke orun,
Je kin won ri ’bi ’simi,
Kin won j’ oko tutu yoyo,
kin won m’ omi ife Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 450 - Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re
This is Yoruba Anglican hymns, APA 450- Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals