Yoruba Hymn APA 446 - Eyi l’ ase nla Jehofa

Yoruba Hymn APA 446 - Eyi l’ ase nla Jehofa

Yoruba Hymn  APA 446 - Eyi l’ ase nla Jehofa

APA 446

 1. Eyi l’ ase nla Jehofa,

Yio wa titi lai;

Elese b’ iwo at’ emi,

K’ a tun gbogbo wa bi.


2. Okunkun y’o je ipa wa,

B’ a wa ninu ese;

A ki o ri ijoba Re,

Bi a ko d’ atunbi.


3. Bi baptisi wa je ’gbarun,

Asan ni gbogbo re;

Eyi ko le w’ ese wa nu,

Bi a ko tun wa bi.


4. Wo ise were ti a nse,

Ko ni iranwo Re;

Nwon ko s’ okan wa di otun,/ B’ awa ko d’ atunbi.


5. Lo kuro ninu ese re

Ja ewon Esu nu;

Gba Kristi gbo tokantokan

Iwo o d’ atunbi. Amin.




Yoruba Hymn  APA 446 - Eyi l’ ase nla Jehofa


This is Yoruba Anglican hymns, APA 446- Eyi l’ ase nla Jehofa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم