Yoruba Hymn APA 434 - Mo nkebi on ongbe

Yoruba Hymn APA 434 - Mo nkebi on ongbe

 Yoruba Hymn  APA 434 - Mo nkebi on ongbe

APA 434

1. Mo nkebi on ongbe,

 Jesu, se onje mi;

 Tu jade, om’ iye,

 Lat’ inu apata.


2. ‘Wo akara t’ a bu,

 Te okan mi l’ orun,

 B’ a ti b’ okan iye,

 Bo mi, ma je ki nku.


3. ‘Wo, Ajara iye,

 Je ki mmo adun Re,

 Jo, tun okan mi se,

 Fi ife s’ aiya mi.


4. Ona aikuna po,

 ‘Ti mo ti rin koja;

 No mi, ONje orun,

 Gba mi, Om’ Olorun.


5. Aginju wa sibe,

 Ti y’o m’ ongbe gbe mi;

 Enyin Omi iye

 E ma sun ninu mi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 434 - Mo nkebi on ongbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 434- Mo nkebi on ongbe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم