Yoruba Hymn APA 422 - Alabukun n’nu Jesu

Yoruba Hymn APA 422 - Alabukun n’nu Jesu

Yoruba Hymn  APA 422 - Alabukun n’nu Jesu

APA 422

 1. Alabukun n’nu Jesu

 Ni awon om’ Olorun,

 Ti a fie je Re ra

 Lat’ inu iku s’iye;

 A ba je ka wa mo won,

 L’aiye yi, ati l’orun.


2. Awon ti a da l’are

 Nipa ore-ofe Re;

 A we gbogbo ese won,

 Nwon o bo l’ojo ’dajo;

 A ba je ka wa, &c.


3. Nwon ns’eso ore-ofe;

 Ninu ise ododo,

 Irira l’ese si won,

 Or’ Olorun ngbe ’nu won;

 A ba je ka wa, &c.


4. Nipa ej’ Odagutan,

 Nwon mba Olorun kegbe,

 Pelu Ola-nla Jesu,

 A wo won l’aso ogo;

 A ba je ka wa, &c. Amin.



Yoruba Hymn  APA 422 - Alabukun n’nu Jesu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 422- Alabukun n’nu Jesu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم