Yoruba Hymn APA 362 - Larin ewu at’ osi

Yoruba Hymn APA 362 - Larin ewu at’ osi

 Yoruba Hymn  APA 362 - Larin ewu at’ osi

APA 362

1. Larin ewu at’ osi,

 Kristian, ma tesiwaju;

 Roju duro, jija na,

 K’ onje ’ye mu o lokun.


2. Kristian, ma tesiwaju,

 Wa k’a jeju ko ota:

 E o ha beru ibi?

 S’e moyi Balogun nyin?


3. Je ki okan nyin k’o yo:

 Mu ’hamora orun wo:

 Ja, ma ro pe ogun npe,

 Isegun nyin fere de.


4. Ma je k’inu nyin baje,

 On fe n’ omije nyin nu;

 Mase je k’eru ba nyin,

 B’ aini nyin, l’ agbara nyin.


5. Nje, e ma tesiwaju,

 E o ju Asegun lo;

 B’ op’ ota dojuko nyin,

 Kristian, e tesiwaju. Amin.



Yoruba Hymn  APA 362 - Larin ewu at’ osi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 362-  Larin ewu at’ osi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم