Yoruba Hymn APA 352 - Ewa ’tanna oro kutu
APA 352
1. Ewa ’tanna oro kutu,
’Mole osan gangan,
Pipon orun li ojoro,
Nwon ti nyara sa to!
A nfe enubode orun,
Ita wura didan:
Awa nfe Orun Ododo,
Ti ki wo titi lai.
2. B’ ireti giga wa laiye
Ti ntele saki to!
Abawon melomelo ni
Nb’ agbada Kristian je?
A nfe okan ti ki dese:
Okan ti a we mo:
Ohun lati yin Oba wa,
Losan-loru titi.
3. Nihin ’gbagbo on ’reti mbe,
Lati to wa soke;
Lohun, pipe alafia
Ju b’a ti le fe lo:
Nipa ife on ’rora Re,
Nitori iku Re,
Ma je k’a subu lona Re,
K’a so ade wa nu. Amin.
Yoruba Hymn APA 352 - Ewa ’tanna oro kutu
This is Yoruba Anglican hymns, APA 352- Ewa ’tanna oro kutu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals