Yoruba Hymn APA 292 - Iwo Oro Olorun
APA 292
1. Iwo Oro Olorun,
Ogbon at’ oke wa,
Oto ti ki ‘yapada,
Imole aiye wa:
Awa yin O fun ‘mole,
T’ inu Iwe mimo;
Fitila fun ese wa,
Ti ntan titi aiye.
2. Oluwa l’ o f’ ebun yin
Fun Ijo Re l’ aiye;
A ngbe ‘mole na soke
Lati tan y’ aiye ka.
Apoti wura n’ ise,
O kun fun Otitio;
Aworan Kristi si ni,
Oro iye toto.
3. O nfe lele b’ asia,
T’ a ta loju ogun;
O ntan b’ ina alore,
Si okunkunn aiye;
Amona enia ni,
Ni wahala gbogbo
Ninu arin omi aiye,
O nto wa sodo Krist.
4. Olugbala, se ‘jo Re,
Ni fitila wura;
Lati tan imole Re,
Bi aiye igbani;
Ko awon ti o sako,
Lati lo ‘mole yi;
Tit’ okun aiye y’ o pin,
Ti nwon o r’oju Re. Amin.
Yoruba Hymn APA 292 - Iwo Oro Olorun
This is Yoruba Anglican hymns, APA 292- Iwo Oro Olorun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals