Yoruba Hymn APA 202 - Okun l’ ale, tutu n’ ile

Yoruba Hymn APA 202 - Okun l’ ale, tutu n’ ile

Yoruba Hymn  APA 202 - Okun l’ ale, tutu n’ ile

 APA 202

1. Okun l’ ale, tutu n’ ile,

 Nibi Kristi wole,

 Ogun Re bi iro eje,

 Ninu ’waya ija.


2 “Baba gb’ ago kikoro yi,

 B’ o ba se ife Re;

 Bi beko, Emi o si mu,

 Ife Re ni k’ a se.”


3. Elese lo wo l’ agbala,

 Eje mimo wonni:

 O r’ eru wuwo ni fun o,

 O re ’ra ’le fun o.


4. Ko lati gbe agbelebu,

 Se ife ti Baba;

 Nigba idanwo sunmole,

 Ji, sora, gbadura. Amin.


APA II


1. Ki Jesu ha nikan jiya,

 K’ araiye lo lofo?

 Iya mbe f’olukuluku;

 Iya si mbe fun mi.


2. Em’ o ru agbelebu mi,

 Tit’ iku y’o gba mi;

 ’Gban, ngo lo ’le lo d’ ade,

 ‘Tor’ ade mbe fun mi.


3. Nile ita Kristali na,

 Leba ese Jesu,

 Ngo f’ ade wura mi lele;

 Ngo yin oruko Re.


4. A! agbelebu! A! ade!

 A! ojo ajinde!

 Enyin Angel, e sokale,

 Wag be okan mi lo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 202 - Okun l’ ale, tutu n’ ile

This is Yoruba Anglican hymns, APA 202 -  Okun l’ ale, tutu n’ ile  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم