Yoruba Hymn APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi
APA 196
1. “Hosanna s’Omo Dafidi:”
Hosanna! e korin!
“Olubukun l’eniti mbo
Loruko Oluwa.”
2. “Hosanna s’Omo Dafidi:”
L’egbe Angeli nke;
Gbogb’ eda, e jumo gberin,
Hosonna s’Oba wa.
3. Hosanna! awon Heberu
Ja im’ope s’ona ;
Hosanna! a mu ebun wa
Fi tun ona Re se.
4. T’agba t’ewe nke, Hosanna!
K’ijiya Re to de;
L’oni, a si nko Hosanna!
B’o ti njoba loke.
5. B’o ti gba ’yin won nigbana,
Jo, gba ebe wa yi!
Lorun, k’a le b’Angel korin,
Hosanna s’Oba wa. Amin.
Yoruba Hymn APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi
This is Yoruba Anglican hymns, APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals