Yoruba Hymn APA 187 - Mokandilogorun dubule je

Yoruba Hymn APA 187 - Mokandilogorun dubule je

Yoruba Hymn  APA 187 - Mokandilogorun dubule je

APA 187

 1. Mokandilogorun dubule je

 Labe oji nin’ agbo;

 Sugbon okan je lo or’ oke,

 Jina s’ ilekun wura :

 Jina rere lor’ oke sisa,

 Jina rere s’ Olusagutan.


2. “Mokandilogorunn Tire l’ eyi :

 Jesu, nwon ko ha to fun O?”

 Olusagutan dahun, “Temi yi

 Ti sako lo lodo mi;

 B’ ona tile ri palapala,

 Ngo w’ aginju lo w’ agutan mi”


3. Okan nin’ awon t’ a ra pada,

 Ko mo jijin omi na;

 Ati dudu oru ti Jesu koja,

 K’ o to r’ agutan Re he;

 L’ aginju rere l’o gbo ’gbe re,

 O ti re tan, o si ti ku tan.


4. “Nibo ni eje ni ti nakn wa,

 T’ o f’ ona or’ oke han ?

 “ A ta sile f’ enikan t’o sako,

 K’ Olusagutan to mu pada.”

 “Jesu kil’ o gun owo Re be ?”

 “Egun pupo l’ o gun mi nibe.”


5. Sugbon ni gbogbo ori oke

 Ati lori apata,

 Igbe ta d’ oke orun wipe,

 “Yo mo r’ agutan mi he.”

 Yite ka l’ awon angel ngba,

 “Yo, Jesu m’ ohun Tire pada.” Amin.

Yoruba Hymn  APA 187 - Mokandilogorun dubule je

This is Yoruba Anglican hymns, APA 187 -Mokandilogorun dubule je  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم