Yoruba Hymn APA 181 - Olorun ’yanu ! ona kan
APA 181
1. Olorun ’yanu ! ona kan
Ti o dabi Tire ko si:
Gbogb’ ogo ore-ofe Re,
L’ o farahan bi Olorun.
Tal’ Olorun ti ndariji,
Ore tal’ o po bi Tire ?
2. N’ iyanu at’ ayo l’ a gba
Idariji Olorun wa;
’Dariji f’ ese t’ o tobi,
T’ a f’ eje Jesu s’ edidi.
Tal’ Olorun, &c.
3. Je ki ore-ofe Re yi,
Ife iyanu nla Re yi,
K’o f’ iyin kun gbogbo aiye,
Pelu egbe Angel l’ oke.
Tal’ Olorun, &c. Amin.
Yoruba Hymn APA 181 - Olorun ’yanu ! ona kan
This is Yoruba Anglican hymns, APA 181- Olorun ’yanu ! ona kan . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.