Yoruba Hymn APA 158 - Olorun, fi opa Re
APA 158
1. Olorun, fi opa Re
Ba mi li ori jeje,
Dawo ’binu Re duro,
Kim ma subu labe re.
2. Wo ailera mi yi san,
Wo mi, mo nwa ore Re;
Eyi nikan l’ ebe mi,
Wo mi, nipa anu Re.
3. Tal’ o wa n’ isa-oku,
T’ o le so ti gbala Re ?
Oluwa, d’ okan mi ro,
Fohun, emi o si ye
4. Wo ! o de ! o gb’ ebe mi,
O de ! ojiji koja;
Ogo sit un yi mi ka,
Okan mi, dide, k’ o yin. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 158 - Olorun, fi opa Re . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.