Yoruba Hymn APA 148 - Baba wa orun npe

Yoruba Hymn APA 148 - Baba wa orun npe

 Yoruba Hymn  APA 148 - Baba wa orun npe

APA 148

1. Baba wa orun npe,

 Krist npe wa sodo Re;

 Ore wa pelu won o dun,

 ’Dapo wa y’o s’ owon.


2. Olorun nkanu mi;

 O dar’ ese mi ji,

 Olodumare s’ okan mi,

 O f’ ogbon to ’pa mi.


3. Ebun Re tip o to !

 O l’ opo isura,

 T’ a t’ owo Olugbala pin,

 Ti a f’ eje Re ra !


4. Jesu Ori ’ye mi,

 Mo fi bukun fun O;

 Alagbawi lodo Baba,

 Asaju lodo Re.


5. Okan at’ ife mi,

 E duro je nihin;

 Titi ’dapo yio fi kun

 L’ oke orun l’ ohun. Amin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 148 - Baba wa orun npe . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم