Yoruba Hymn APA 142 - Kristi sun f’ elese

Yoruba Hymn APA 142 - Kristi sun f’ elese

 Yoruba Hymn  APA 142 -  Kristi sun f’ elese

APA 142

1. Kristi sun f’ elese,

 Oju wa o gbe bi ?

 K’ omi ’ronu at’ ikanu,

 Tu jade l’ oju wa.


2. Omo Olorun nsun,

 Angeli siju wo !

 K’ o damu, iwo okan mi,

 O d’ omi ni fun o.


3. O sun k’ awa k’o sun,

 Ese bere ekun:

 Orun nikan ni ko s’ ese,

 Nibe ni ko s’ ekun. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 142 -  Kristi sun f’ elese . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم