Yoruba Hymn APA 141 - Jesu, l’ojo anu yi

Yoruba Hymn APA 141 - Jesu, l’ojo anu yi

Yoruba Hymn  APA 141 - Jesu, l’ojo anu yi

APA 141

 1. Jesu, l’ojo anu yi,

 Ki akoko to koja,

 A wole ni ekun wa.


2. Oluwa, m’ekun gbon wa,

 Fi eru kun aiya wa,

 Ki ojo iku to de.


3. Tu Emi Re s’okan wa,

 L’enu-ona Re l’a nke;

 K’ilekun anu to se.


4. ’Tori ’waiya-ija Re,

 ’Tori ogun-eje Re,

 ’Tori iku Re fun wa,


5. ’Tor’ ekun kikoro Re,

 Lori Jerudalemu,

 Ma je k’a gan ife Re.


6. Iwo Onidajo wa,

 ’Gbat’ oju wa ba ri O,

 Fun wa n’ipo lodo Re.


7. Ife Re l’a simi le,

 N’ile wa l’oke l’ao mo

 B’ife na tit obi to. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 141 - Jesu, l’ojo anu yi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم