Yoruba Hymn APA 136 - Krist’, ki ’joba Re de

Yoruba Hymn APA 136 - Krist’, ki ’joba Re de

 Yoruba Hymn  APA 136 - Krist’, ki ’joba Re de

APA 136

1. Krist’, ki ’joba Re de,

 Ki ase Re bere;

 F’ opa-irin Re fo

 Gbogbo ipa ese.


2. Ijoba ife da,

 Ati t’ Alafia?

 Gbawo ni irira

 Yio tan bi t’orun?


3. Akoko na ha da,

 T’ ote yio pari,

 Ika at’ ireje,

 Pelu ifekufe?


4. Oluwa jo, dide,

 Wa n’ nu agbara Re;

 Fi ayo fun awa

 Ti o nsaferi Re.


5. Eda ngan oko Re,

 Koko nje Agbo Re;

 Iwa ’tiju pupo

 Nfihan pe ’fe tutu.


6. Okun bole sibe,

 Ni ile keferi:

 Dide ’Rawo oro,

 Dide, mase wo mo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 136 -  Krist’, ki ’joba Re de  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم