Yoruba Hymn APA 119 - Keferi nsegbe lojojo

Yoruba Hymn APA 119 - Keferi nsegbe lojojo

Yoruba Hymn  APA 119 - Keferi nsegbe lojojo

APA 119

 1. Keferi nsegbe lojojo,

 Egbegberun l’ o nkoja lo,

 Mura Kristian s’ igbala won

 Wasu fun won, kin won to ku.


2. Oro, owo, e fi tore

 Na, k’ e sin a kin won le ye;

 Ohun ti Jesu se fun nyin,

 Kil’ enyin ki ba se fun On ? Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 119 - Keferi nsegbe lojojo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم