Yoruba Hymn APA 117 - Gbo ! eredi ekun wonyi

Yoruba Hymn APA 117 - Gbo ! eredi ekun wonyi

 Yoruba Hymn  APA 117 - Gbo ! eredi ekun wonyi

APA 117

1. Gbo ! eredi ekun wonyi,

 Ti a ngbo kiri aiye ?

 Ekun awon keferi ni

 Pe, “Gba wa k’ awa to ku.”


2. Gb’ aroye awon keferi,

 Kristian, gbo ’gbe iku won;

 Je k’ ife Kristi k’ o ro nyin,

 K’ e gba won ki nwon toku. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 117 -  Gbo ! eredi ekun wonyi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم