Yoruba Hymn APA 112 - Gbo ! orin ti Jubeli

Yoruba Hymn APA 112 - Gbo ! orin ti Jubeli

Yoruba Hymn  APA 112 - Gbo ! orin ti Jubeli

APA 112

1. Gbo ! orin ti Jubeli,

 O dabi sisan ara;

 Tabi bi kikun okun

 Gbat’ igbi re ba nlu ’le

 Halleluia ! Olorun

 Olodumare joba:

 Halleluia ! k’ oro na

 Dun yi gbogbo aiye ka.


2. Halleluia ! – gbo iro,

 Lati aiye de orun,

 Nji orin gbogbo eda,

 L’oke, nisale, yika,

 Wo, Jehofa ti ete

 Ida w’ako ;- o pase,

 Awon ijoba aiye

 Di ijoba Omo Re.


3. Y’o joba yi aiye ka,

 Pelu agbara nlanla;

 Y’o joba ’gbati orun,

 At’ aiye ba koja lo:

 Opin de: lab’ opa Re,

 L’ota enia subu:

 Halleluia ! Olorun

 Ni gbogbo l’ohun gbogbo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 112 -  Gbo ! orin ti Jubeli . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم