Yoruba Hymn APA 105 - Wo Omo ayanfe Baba
APA 105
1. ’Wo Omo ayanfe Baba,
Wa lati gba ile ini,
Ti Baba ti pamo lailai
Fun ijoba Re ailopin.
2. Wa f’ ara Re han araiye
Wa ki gbogbo won juba Re;
Niwaju Re, gbogbo ahon Ni y’o jewo itoye Re.
3. Awon t’ o wa n’ ila-orun
Egbegberun ! nwon tip o to !
Pelu awon t’ iwo-orun
Yio sin Oba ologo.
4. Gbogbo ariwa, on gusu,
Yio pe oruko nla Re;
Keferi, ati Ju pelu
Nwon o wa s’ abe oye Re.
5 Okunkun su bo won mole;
Olrun Oluwa ’mole,
Tan imole Ihin-rere
Ka gbogbo orile-ede.
6. Yara je ki ’joba Re de,
Gbo adura yi, Oluwa;
Ti gbogbo eya at’ ede
Y’o fi mo O l’ olugbala. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 105 - Wo Omo ayanfe Baba . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.