Yoruba Hymn APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun

Yoruba Hymn APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun

 Yoruba Hymn APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun

APA 80

1. Wo ! gbogbo ile okunkun,

 Wo ! okan mi, dro je;

 Gbogbo ileri ni o nso

 T’ ojo ayo t’o l’ogo;

 Ojo ayo ! Ojo ayo !

 K’ owuro re yara de !


2. Ki India on Afrika,

 K’ alaigbede gbogbo ri

 Isegun nla t’ o logo ni,

 T’ ori oke Kalfari;

 K’ ihinrere, K’ ihinrere

 Tan lat’ ilu de ilu.


3. Ijoba t’ o wa l’ okunkun,

 Jesu, tan ’mole fun won.

 Lat’ ila-orun de ’wo re,

 K’ imole le okun lo;

 K’ irapada, k’ irapada,

 Ti a gba l’ ofe bori.


4. Ma tan lo, ’wo ihinrere,

 Ma segun lo, ma duro:

 K’ ijoba re aiyeraiye

 Ma bi si, k’ o si ma re;

 Olugbala, Olugbala,

 Wa joba gbogbo aiye. Amin.

Yoruba Hymn APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 80 - Wo ! gbogbo ile okunkun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم