Yoruba Hymn APA 1- Ji, okan mi, ba orun ji

Yoruba Hymn APA 1- Ji, okan mi, ba orun ji

 Yoruba Hymn APA 1- Ji, okan mi, ba orun ji

APA I

1. Ji, okan mi, ba orun ji,

 Mura si ise ojo re;

 Ma se ilora, ji kutu,

 K’ o san gbese ebo oro.


2. Ro gbogb’ ojo t’ o fi sofo;

 Bere si rere ’se loni;

 Kiyes’ irin re laiye yi;

 K’ o si mura d’ ojo nla ni.


3. Gba ninu imole orun,

 Si tanmole na f’elomi:

 Je ki ogo Olorun re

 Han n’nu iwa at’ ise re.


4. Ji, gbon’ra nu, ’wo okan mi,

 Yan ipo re larin Angel,

 Awon tin won nkorin iyin

 Ni gbogbo oru s’ Oba wa. Amin.


This is Yoruba Anglican hymns, APA 1 - Ji, okan mi, ba orun ji. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم