Yoruba Hymn APA 65 - Onidajo na de, O de
APA 65
1. Onidajo na de, O de !
Beni ’pe keje tin dun nwi,
Manamana nko, ara nsan,
Onigbagbo y’o ti yo to !
2. A ngbo, Angel orun nwipe,
Jesu Oluwa wa d’ ade,
Or’-ofe l’ On fi damure,
Ogo l’ On fi s’ oso boju.
3. ’Wo sokale lor’ ite Re,
O gba ijoba fun ’ra Re;
Ijoba gbogbo gba Tire,
Nwon gba b’ Oluwa t’ o segun.
4. Gbogbo ara orun, e ho,
At’ enia; Oluwa wa,
Oga ogo t’ o gba ola
Yio job alai ati lai. Amin.
Yoruba Hymn APA 65 - Onidajo na de, O de
This is Yoruba Anglican hymns, APA 65 - Onidajo na de, O de. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.