Yoruba Hymn APA 55 - Oluwa mbo; aiye o mi

Yoruba Hymn APA 55 - Oluwa mbo; aiye o mi

Yoruba Hymn  APA  55- Oluwa mbo; aiye o mi

APA 55

1. Oluwa mbo; aiye o mi,

 Oke y’o sidi n’ ipo won;

 At’ irawo oju orun,

 Y’o mu imole won kuro.


2. Oluwa mbo; bakanna ko

 Bi o ti wa n’ irele ri;

 Odo-agutan ti a pa,

 Eni-iya ti o si ku.


3. Oluwa mbo; li eru nla

 L’ owo ina pelu ija

 L’or’ iye apa Kerubu,

 Mbo, Onidajo araiye.


4. Eyi ha li eniti nrin,

 Bi ero l’ opopo aiye?

 Ti a se ’nunibibi si?

 A ! Eniti a pa l’ eyi?

 

5. Ika; b’ e wo ’nu apata,

 B’ e wo nu iho, lasan ni;

 Sugbon igbagbo t’ o segun,

 Y’o korin pe, Oluwa de. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 55 - Oluwa mbo; aiye o mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم