Yoruba Hymn APA 51 - Ojo ’binu, ojo eru
APA 51
1. Ojo ’binu, ojo eru
T’ aiye at’ orun y’o folo,
Kin’ igbekele elese?
Y’o se le yoju l’ojo na?
2. Nigbati orun y’o kako
Bi awo ti a f’ ina sun;
T’ ipe ajinde o ma dun
Kikankikan, teruteru.
3. A ! l’ojo na, ojo ’b inu,
T’ eda yio ji si ’dajo,
Kristi, jo se ’gbekele wa
’Gba t’aiye t’orun ba folo. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 51 - Ojo ’binu, ojo eru. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.