Yoruba Hymn 48 APA - Gbo ’gbe ayo ! Oluwa de

Yoruba Hymn 48 APA - Gbo ’gbe ayo ! Oluwa de

 Yoruba Hymn 48 APA - Gbo ’gbe ayo ! Oluwa de

APA 48

 1. Gbo ’gbe ayo ! Oluwa de,

 Jesu t’a seleri;

 Ki gbogbo okan mura de,

 K’ ohun mura korin.


2. O de lati t’ onde sile

 L’ oko eru Esu;

 ’Lekun ’de fo niwaju Re.

 Sekeseke ’rin da.

3. O de larin ’baje aiye

 Lati tan ’mole Re,

 Lati mu k’awon afoju

 Le f’oju won reran.


4. Ode, ’tunu f’okan ’rora,

 Iwosan f’agbogbe;

 Pelu ’sura or’ ofe Re

 Fun awon talaka.

 

5. Hosanna, Oba ’Lafia,

 Ao kede bibo Re;

 Gbogbo orun y’o ma korin

 Oruko t’a feran. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 48 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم