Yoruba Hymn APA 36 - Ayo l’ ojo ’simi fun mi

Yoruba Hymn APA 36 - Ayo l’ ojo ’simi fun mi

 Yoruba Hymn  APA 36 - Ayo l’ ojo ’simi fun mi

APA 36

 1. Ayo l’ ojo ’simi fun mi,

 At’ agogo at’ iwasu:

 Gbat’ a ba mi n’nu ’banuje

 Awon l’o nmu inu mi dun.


2. Ayo si ni wakati na

 Ti mo lo n’nu agbala Re;

 Lati mo adun adura

 Lati gba manna oro Re.


3. Ayo ni idahun “Amin”

 T’o gba gbogbo ile na kan,

 Lekokan l’o ndun t’ o nrole,

 O nkoja lo sodo Baba.

 

4. B’ aiye fe f’ agbara de mi

 Mo ise ijo mefa re;

 Oluwa, jo, tu ide na,

 K’ o so okan mi d’ominira. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 36 - Ayo l’ ojo ’simi fun mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم