Yoruba Hymn APA 35 - Akoko odun at’ osu

Yoruba Hymn APA 35 - Akoko odun at’ osu

 Yoruba Hymn  APA 35- Akoko odun at’ osu

APA 35

 1. Akoko odun at’ osu,

 Gbogbo won l’ Olorun da;

 Ojumo ni fun ise wa,

 Oru si ni lati sun.


2. O si da ojo isimi;

 N’nu ’jo meje, O mu ’kan,

 K’ enia ba le r’ aye se

 Ati sin Olorun wa.


3. L’ ojo mefa ni k’ a sise,

 B’ o ti ye ni ki a se;

 L’ ojo keje je k’ a pejo,

 Ni ile Olorun wa.


4. L’ ojo na yi a ngbadura,

 A nkorin didun si I

 A sin yin Olorun l’ ogo,

 T’ o ju ohun gbogbo lo.

 

5. Nisisiyi korin iyin,

 T’ Olorun Oluwa wa:

 Korin didun, korin soke,

 Ni yiyin Oluwa wa. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 35 - Akoko odun at’ osu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم