Yoruba Hymn APA 32 - Nigbawo Olugbala mi
APA 32
1. Nigbawo Olugbala mi,
L’ emi o ri O je?
N’ isimi t’ o ni ibukun,
Laisi ’boju larin.
2. Ran mi lowo n’ irinkiri,
L’ aiye aniyan yi:
Se mi ki nfi ’fe gbadura
Si gba adura mi.
3. Da mi si, Baba, da mi si,
Mo f’ara mi fun O;
Gba ohun gbogbo ti mo ni,
Si f’ ara Re fun mi.
4. Emi re, Baba, fifun mi,
K’ o le ma pelu mi;
K’ o se imole ese mi
S’ isimi ailopin. Amin.
Yoruba Hymn APA 32 - Nigbawo Olugbala mi
This is Yoruba Anglican hymns, APA 32 - Nigbawo Olugbala mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.