Yoruba Hymn APA 30- Jesu, a fe pade

Yoruba Hymn APA 30- Jesu, a fe pade

Yoruba Hymn APA  30- Jesu, a fe pade

APA 30

1. Jesu, a fe pade,

 L’ ojo Re mimo yi;

 A si y’ ite Re ka,

 L’ ojo Re mimo yi:

 ’Wo ore wa orun,

 Adura w ambo wa,

 Bojuwo emi wa

 L’ ojo Re mimo yi.


2. A ko gbodo lora,

 L’ ojo Re mimo yi:

 Li eru a kunle,

 L’ ojo Re mimo yi:

 Ma taro ise wa,

 K’ iwo k’ o si ko wa,

 K’ a sin O b’ o ti ye

 L’ ojo Re mimo yi.

 

3. A teti s’ oro Re

 L’ ojo Re mimo yi;

 Bukun oro t’ a gbo,

 L’ ojo Re mimo yi;

 Ba wa lo ’gba t’ a lo,

 F’ ore igbala Re

 Si aiya wa gbogbo,

 L’ ojo Re mimo yi. Amin.

Yoruba Hymn APA  30- Jesu, a fe pade

This is Yoruba Anglican hymns, APA 30 - Jesu, a fe pade. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم