Yoruba Hymn APA 29- Oluwa ojo isimi
APA 29
1. Oluwa ojo isimi,
Gbo ti wa, pelu wa loni;
Awa pade fun adura,
A fe gb’ oro t’ o fi fun wa.
2. Isimi t’ aiye yi rorun,
Sugbon isimi t’ ohun dun:
Lala okan wa fe ’jo na,
T’ a o simi lailese da.
3. Ko si ’ja, ko si ’dagiri,
Ko s’ aniyan bi t’ aiye yi
T’ y’o dapo mo ikorin wa
T’ o nt’ ete aiku jade wa.
4. Bere, ojo t’ a ti nreti,
Afemoju re l’ a fe ri;
A fey o lona ise yi
K’ a sun n’ iku, k’ a ji l’ ayo. Amin.
Yoruba Hymn APA 29- Oluwa ojo isimi
This is Yoruba Anglican hymns, APA 29 - Oluwa ojo isimi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.