Yoruba Hymn APA 28 - A be, a fe ri O

Yoruba Hymn APA 28 - A be, a fe ri O

 Yoruba Hymn APA 28 - A be, a fe ri O

APA 28

 1. A be, a fe ri O

 Ojo ’simi rere

 Gbogbo ose ama wipe

 Iwo o ti pe to !


2. O ko wa pe Kristi

 Jinde ninu oku;

 Gbogbo ose ama wipe,

 Iwo o ti pe to !


3. O so t’ ajinde wa

 Gege bi ti Jesu;

 Gbogbo ose ama wipe,

 Iwo o ti pe to !

 

4. Iwo so t’ isimi

 T’ ilu Alafia;

 T’ ibukun enia mimo

 Iwo o ti pe to ! Amin.

Yoruba Hymn APA  28 - A be, a fe ri O

This is Yoruba Anglican hymns, APA 28 - A be, a fe ri O. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


إرسال تعليق (0)
أحدث أقدم